Magun lyrics

Songs   2025-01-10 13:47:16

Magun lyrics

Nini dey o eh

Shine shine baby

Characteristics of party

Ra o ri mi fun osu meta, ra o ri mi sheke

To jun mi fun osu meta, to jun mi sheke

Ki ma gba owo, ori mi ma je ko baje

To ba pe I would koja there

Ko ja si cuddle bo da le

Owo meta, ika meta fowo si mi laya

Owo meta, ika meta fowo si mi lahan

Owo meta, ika meta fowo si mi ni imu

Owo meta, ika meta fowo si mi Lara

Magun le leyi

Magun (don’t touch)

Magun

Magun le leyi

Magun le leyi

Magun le leyi

Magun

Magun

Magun, magun

Magun, magun eh

O lewu fu anybody to ba fe gun mi

Mo fi magun sara to protect the body

Ere egele on a surface level

Only foreplay is allowed for you my darling

Ra o ri mi fun osu meta, ra o ri mi sheke

To jun mi fun osu meta, to jun mi sheke

Mo gbo pe oti se 3 3 threesome

Mo gbo pe oti se 3 3 threesome

Owo meta, ika meta fowo si mi laya

Owo meta, ika meta fowo si mi lahan

Owo meta, ika meta fowo si mi ni imu

Owo meta, ika meta fowo si mi lara

Magun le leyi

Magun (don’t touch)

Magun

Magun le leyi

Magun le leyi

Magun le leyi

Magun

Magun

Magun, magun

Magun, magun eh

Magun le leyi

Magun (don’t touch)

Magun

Magun le leyi

Magun le leyi

Magun le leyi

Magun

Magun

Magun, magun

Magun, magun eh

  • Artist:Niniola
  • Album:This Is Me (2017)
See more
Niniola more
  • country:Nigeria
  • Languages:Yoruba, English, English (Nigerian Pidgin)
  • Genre:
  • Official site:https://www.officialniniola.com
  • Wiki:
Niniola Lyrics more
Excellent Songs recommendation
Popular Songs
Copyright 2023-2025 - www.lyricf.com All Rights Reserved